Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé fún Olúkúlùkù Orílẹ̀-èdè lórí Pílánẹ́ẹ̀tì

Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé fún Olúkúlùkù Orílẹ̀-èdè lórí Pílánẹ́ẹ̀tì

'Láti Aramaic sí Zulu: Ìwé aláwòrán Ǹjẹ́ mo kéré? náà ni a ti tumọsi èdè àti ẹ̀ka tí ó lé ní 200 lati ìgbà tí wọ́n ti tẹ jade.

Ìtàn náà láti òǹkọ̀wé Philipp Winterberg wà larọwọọto fún gbogbo orílẹ̀-èdè lágbàáyé ó kéré tán ní èdè àjùmọ̀lò kan. O jẹ ìwé ọmọdé àkọ́kọ́ tí àgbáyé tí ó kárí gbogbo obirikiti ilẹ-aye.

Ǹjẹ́ mo kéré? àwọn òǹkàwé àtèwe-àtàgbà bákan náà tẹ̀ lé ọmọbìnrin náà Tamia rin ìrìn àjò tó kún fún àwọn ohun ìyanu. Wọ́n jọ ṣàwárí pé ìwọ̀n ní ààlà àti pé Tamia tọ̀nà gan-an lọ́nà tó wá. “Alárinrin” ni ìdájọ́ ìwé ìròyìn ìṣòwò Eselsohr, “àgbàyanu gidigidi fún àwọn ìdílé elédè méjì, àti àwọn ọmọ ilé ìwé jẹ́lé-ó-sinmi,” ni Börsenblatt sọ àti ìwé ìròyìn alàtúnyẹ̀wò náà Kirkus Reviews fohùn jẹ́jẹ́ ṣe àpọ́nlé “fún àwọn ọmọdé tí wọ́n gbádùn láti máa dúró lórí ojú ìwé tó kún fún àwọn ẹ̀dá onídán àti àwọn àlàyé aibọgbọnmu [...]tí wọ́n sọ ni àwọn ọ̀rọ̀ ṣókí àti àwọn ọ̀rọ̀ tí ń gbà ni lọ́kàn àti àwọn àwòrán ìdánúṣe.”

'Àwọn olùtumọ̀ èdè tó lé ní 400 ti kópa tẹlẹ nínú Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé náà. Nígbà míràn ìwádìí náà gba oṣù púpọ̀, “Mo nilati wá olùtumọ̀ èdè tí ilẹ̀ Tibet fún nǹkan bí ọdún kan,” ni Winterberg sọ.

Ìwé náà ti wà larọọwọto pẹlu ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn àpapọ̀ èdè, bí Arabic-Tagalog tàbí Portuguese-Tigrinya — èdè tí wọ́n sọ lórílẹ̀-èdè Ethiopia àti Eritrea, ti ìwé-àfọwọ́kọ rẹ jẹ ránni létí iyàwòrán àwọn ọmọdé.

Ní ọdún àti èwádún tí ń bọ, iṣẹ́ àkànṣe Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé yóo máa pọ̀ sí i. Ètè náà jẹ́ láti túmọ̀ Ǹjẹ́ mo kéré? sí onírúurú èdè àti ẹ̀ka tí ó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta.

Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé fún Olúkúlùkù Orílẹ̀-èdè lórí Pílánẹ́ẹ̀tì
Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé fún Olúkúlùkù Orílẹ̀-èdè lórí Pílánẹ́ẹ̀tì
Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé fún Olúkúlùkù Orílẹ̀-èdè lórí Pílánẹ́ẹ̀tì

200+ èdè

📖   Anu maay uxxiyo? (Afar)

📖   Is ek klein? (Afrikaans)

📖   Meyɛ ketewa anaa? (Akan/Twi/Asante)

📖   A jam e vogël? (Albanian)

📖   እኔ ትንሽ ነኝ? (Amharic)

📖   我细汉系? (Chinese/Min Chinese/Amoy Dialect)

📖   Amʊn naa saa gʊŋɛ aà? (Anii/Gisida/Bassila/Baseca/Akpe)

📖   هل أنا صغيرة؟ (Arabic)

📖   هل أنا صغيرة؟ (Egyptian Arabic/Masri)

📖   هل أنا صغيرة؟ (Gulf Arabic/el-lahja el-Khalijiyya)

📖   هل أنا صغيرة؟ (Levantine Arabic)

📖   واش أنا صغيرة؟ (Maghrebi Arabic/Moroccan Dialect/Darija)

📖   Soi chicota? (Aragonese)

📖   انا زشعتا؟ (Aramaic/Eastern Aramaic/Mandaic)

📖   Ես փոքրի՞կ եմ: (Armenian)

📖   ¿Soi pequeña? (Asturian)

📖   মই সৰু নেকি? (Assamese)

📖   ¿Jisk’asktti? (Aymara/Central Aymara)

📖   Mən balacayam? (Azerbaijani)

📖   Awak tyang cenik nggih? (Balinese/Bali)

📖   Wala ne ka dɔgɔ wa? (Bambara)

📖   Txikia naiz? (Basque)

📖   Ці я маленькая? (Belarusian)

📖   আমি কি ছোট? (Bengali)

📖   Sadit ba ako? (Bicolano/Bikol/Coastal Bikol/Bikol Naga)

📖   Da li sam malena? (Bosnian)

📖   Ha gwir eo on bihan ? (Breton)

📖   Малка ли съм? (Bulgarian)

📖   ငါက သေးငယ်လား? (Burmese/Myanmar)

📖   我個子小嗎? (Cantonese/Yue Chinese)

📖   Soc petita? (Catalan)

📖   Poreg sí? (Celinese)

📖   Kao dikike’ yu’? (Chamorro)

📖   Со жима ю? (Chechen)

📖   Ndine mwana? (Chewa/Chichewa/Nyanja)

📖   我小吗? (Chinese/Mandarin Chinese [Simplified])

📖   我細小嗎? (Chinese/Mandarin Chinese [Traditional])

📖   Эпӗ пӗчӗк? (Chuvash)

📖   Mi mtiti? (Comorian)

📖   Ov byghan? (Cornish)

📖   Jesam li ja mala? (Croatian)

📖   Jsem malá? (Czech)

📖   Awjinika? (Damiyaa)

📖   Er jeg lille? (Danish)

📖   آیا من کوچک هستم؟ (Dari/Afghan Persian/Farsi)

📖   އަހަރެން ކުޑަތަ؟ (Dhivehi/Maldivian)

📖   Kuɔɔr ë ɣɛɛn? (Dinka/South Dinka)

📖   Ben ik klein? (Dutch)

📖   ང་ཆུང་ཀུ་ཨིན་ན་ (Dzongkha)

📖   Am I small? (English)

📖   Ĉu mi estas malgranda? (Esperanto)

📖   Kas ma olen väike? (Estonian)

📖   Ðɛ mɛlɛ sue a? (Ewe)

📖   O au lailai? (Fijian)

📖   Ako ba ay maliit? (Filipino/Tagalog)

📖   Olenko minä pieni? (Finnish)

📖   Ben ik klein? (Flemish)

📖   Je suis petite, moi ? (French)

📖   Mi pamaro? (Fula/Fulani)

📖   Son pequena? (Galician)

📖   მე პატარა ვარ? (Georgian)

📖   Bin ich klein? (German)

📖   Bilewin ilewich kleilewein? (Secret Language/German Spoon Language)

📖   I uarereke ngai? (Gilbertese/Kiribati)

📖   Im leitila? (Gothic)

📖   Είμαι μικρή; (Greek)

📖   Mikingama? (Greenlandic)

📖   Chemichĩ piko che? (Guarani/Paraguayan Guarani)

📖   શું હું નાની છું? (Gujarati)

📖   Eske mwen piti? (Haitian Creole)

📖   Ni ƙarama ce? (Hausa)

📖   Li‘ili‘i wau? (Hawaiian)

📖   ?האם אני קטנה (Hebrew)

📖   Ka gamay sa akon? (Hiligaynon)

📖   क्या मैं छोटी हूँ? (Hindi)

📖   Lau be maraki a? (Hiri Motu/Police Motu/Pidgin Motu)

📖   Kicsi vagyok? (Hungarian)

📖   Er ég lítil? (Icelandic)

📖   Adim obere? (Igbo)

📖   Bassit nak kadi? (Ilocano/Ilokano)

📖   Apakah aku kecil? (Indonesian)

📖   An bhfuil mé beag? (Irish Gaelic)

📖   Io sono piccola? (Italian)

📖   Mi likkle? (Jamaican Patois/Jamaican Creole)

📖   わたしは、ちいさいの? (Japanese)

📖   Apa aku cilik? (Javanese)

📖   ನಾನು ಚಿಕ್ಕವಳೇ? (Kannada)

📖   بُو چَھ لکُٹ ؟ (Kashmiri)

📖   Мен кішкентаймын ба? (Kazakh)

📖   តើខ្ញុំតូចមែនទេ? (Khmer)

📖   ¿In nitz’ na? (K’iche’/Quiché)

📖   Mukele fioti? (Kongo/Kikongo)

📖   Nie ndi munini? (Kikuyu)

📖   Ndi muto? (Kinyarwanda)

📖   Ndi muto? (Kirundi/Rundi)

📖   내가 작니? (Korean)

📖   Ez biçûk im? (Kurdish/Northern Kurdish/Kurmanji)

📖   من بچووکم؟ (Kurdish/Central Kurdish/Sorani)

📖   Мен кичинекейминби? (Kyrgyz)

📖   ڪيا مئين ننڍڙي هان؟ (Southern Lahnda/Siraiki/Seraiki/Saraiki)

📖   ໂຕຂ້ອຍນ້ອຍບໍ? (Lao)

📖   Ego sum parva? (Latin)

📖   Vai es esmu maza? (Latvian)

📖   Naza moke? (Lingala)

📖   Ar aš maža? (Lithuanian)

📖   Bünn ick lüdderk? (Low German/Emslandic)

📖   Ne katshutshu? (Luba-Katanga/Luba-Shaba/Kiluba)

📖   Ndi mutono? (Luganda/Ganda)

📖   Sinn ech kleng? (Luxembourgish)

📖   Мала ли сум? (Macedonian)

📖   Kely ve aho? (Malagasy)

📖   Adakah saya kecil? (Malay)

📖   ഞാൻ ചെറിയതാണോ? (Malayalam)

📖   Jiena żgħira? (Maltese)

📖   He iti rānei ahau? (Maori)

📖   मी छोटी आहे? (Marathi)

📖   Mol ke idik? (Marshallese)

📖   υ:ʌ:-ńɾv (Mila)

📖   Би бяцхан гэж үү? (Mongolian)

📖   Da li sam ja mala? (Montenegrin)

📖   Mam yaa kɩdga? (Mossi)

📖   Lu oe hì’i srak? (Na‘vi)

📖   Oning nga duwo? (Nauruan/Nauru)

📖   के म सानी छु ? (Nepali)

📖   Ban ik latj? (North Frisian)

📖   Toho do ahu geleng? (Northern Batak/Pak-Pak Dairi)

📖   Na ke o monyenyane? (Northern Sotho/Sepedi/Pedi)

📖   Er jeg liten? (Norwegian)

📖   Er eg hjokk? (Nynorn/Norn)

📖   Sei pita ? (Occitan)

📖   କଣ ମୁଁ ଛୋଟ? (Odia/Oriya)

📖   Ani Xiqqoo? (Oromo)

📖   Ngame omushona? (Oshiwambo/Oshindonga Dialect)

📖   Æццæй, æз чысыл дæн? (Ossetian/Ossete/Ossetic)

📖   Ngak ak kekerei? (Palauan)

📖   किं अहं खुद्दकानि? (Pali)

📖   آیا زه کوچنې یم؟ (Pashto/Pukhto)

📖   من کوچیکم؟ (Persian/Farsi)

📖   Czy jestem mała? (Polish)

📖   Sou pequena? (Brazilian Portuguese)

📖   Serei eu pequena? (Portuguese (Portugal))

📖   ਕੀ ਮੈਂ ਨਿੱਕੀ ਹਾਂ? (Punjabi)

📖   ¿Uchuy kanichu? (Quechua/Southern Quechua/Cusco Dialect)

📖   काँई मैं छोटी हूं? (Rajasthani/Shekhawati Dialect)

📖   Sunt eu mică? (Romanian)

📖   Sun jau pitschna? (Romansh/Romansch)

📖   Я маленькая? (Russian)

📖   Ou te la‘ititi? (Samoan)

📖   Bal aan keei yahl? (Sandic)

📖   Mbi yéké kété? (Sango/Sangho)

📖   So pidda? (Sardinian/Sard)

📖   किं अहं प्रतनुः? (Sanskrit)

📖   Um A wee? (Scots/Lowland Scots)

📖   A bheil mi beag? (Scottish Gaelic)

📖   Jesam li ja mala? (Serbian)

📖   Av haa luume? (Seren)

📖   A ke monnye? (Setswana/Tswana)

📖   Mon pti mwan? (Seychellois Creole/Kreol seselwa)

📖   我很小吗? (Shanghainese/Hu/Wu Chinese)

📖   Ndiri muduku here? (Shona)

📖   Sugnu nica iu? (Sicilian/Calabro-Sicilian)

📖   මම පොඩි ද? (Sinhala/Sinhalese)

📖   Som malá? (Slovak)

📖   Ali sem majhna? (Slovenian/Slovene)

📖   Miyaan yarahay? (Somali)

📖   Ngimncinyane yini? (Ndebele/Southern Ndebele/Transvaal Ndebele)

📖   Na ke monyane? (Sesotho [Lesotho]/Southern Sotho)

📖   Na ke monyane? (Sesotho [South Africa]/Southern Sotho)

📖   ¿Soy pequeña? (Spanish)

📖   Gou iq lwi? (Zhuang/Standard Zhuang)

📖   Dupi abdi alit? (Sundanese)

📖   Mimi ni mdogo? (Swahili)

📖   Ngimncane? (Swazi/Swati/siSwati)

📖   Är jag liten? (Swedish)

📖   Bin ich chlii? (Swiss German)

📖   Mea naʻinaʻi au? (Tahitian/Reo Tahiti)

📖   我個頭小嗎? (Taiwanese/Taiwanese Mandarin/Guoyu)

📖   Оё ман хурд астам? (Tajik)

📖   Nec ṭṭamezyant? (Tamazight/Standard Moroccan Berber/Amazigh)

📖   நான் சிறியவளாக இருக்கிறேனா? (Tamil)

📖   నేను చిన్నగా ఉన్నానా? (Telugu)

📖   Ha’u ki’ik ka lae? (Tetum/Tetun Dili)

📖   ฉันตัวเล็กหรือ? (Thai)

📖   ང་ཆུང་ཆུང་རེད་འདུག་གམ། (Tibetan)

📖   አነ ንእሽተይ ድየ? (Tigrinya)

📖   Mi liklik? (Tok Pisin/New Guinea Pidgin)

📖   Kou si’i nai? (Tongan)

📖   U ri ndzi ntsanana? (Tsonga)

📖   Ben küçük müyüm? (Turkish)

📖   Men kiçijikmi? (Turkmen)

📖   Au e foliki? (Tuvaluan/Tuvalu)

📖   Я — маленька? (Ukrainian)

📖   Sym ja małka? (Upper Sorbian)

📖   کیا میں چھوٹی ہوں؟ (Urdu)

📖   مەن كىچىكمۇ؟ (Uyghur/Uighur)

📖   Men kichikmanmi? (Uzbek)

📖   Ndi muṱuku nṋe? (Venda)

📖   Sóc xicoteta? (Valencian)

📖   Có phải tôi nhỏ bé? (Vietnamese)

📖   Ydw i’n fach? (Welsh)

📖   Màn dama tuti? (Wolof)

📖   Ndimncinane? (Xhosa)

📖   ?בין איך קליין (Yiddish)

📖   Ǹjẹ́ mo kéré? (Yoruba)

📖   Ingabe ngimncane na? (Zulu)

🧑

Ọ̀rọ̀ nípa ẹni tó kọ ìwé náà

Philipp Winterberg kẹ́kọ̀ọ́ Ìmọ̀ Ìbánisọ̀rọ̀, Sáyẹ́nsì ọ̀rọ̀-inúọkàn àti Ẹ̀kọ́ Òfin. Ó ń gbé ní Berlin ó sì nífẹ̀ẹ́ láti jẹ́ onírúurú: ó lọ fò pẹ̀lú ohun èlò bí abùradà ní Namibia, ó ṣàṣàrò ní Thailand, ó sì lúwẹ̀ẹ́ pẹ̀lú ẹja ekurá àti ẹja afìrùṣoró ní Fiji àti Polynesia.

Àwọn ìwé Philipp Winterberg ṣàfihàn ojú ìwòye tuntun lórí àwọn ẹṣin ọ̀rọ̀ pàtàkì bíi ìbánidọ́rẹ̀ẹ́, aájò àti ìdùnnú. Wọ́n ń ka wọ́n ní àwọn èdè àti àwọn orílẹ̀-èdè káàkiri àgbáyé.